Enter questions that involve “WHAT” in the box below. Then the translation to Yoruba Language will be displayed. Also displayed is the translation to Etsako Language. Kindly use a mobile device to enjoy the language translation service.
S/N | ENGLISH | YORUBA |
---|---|---|
1 | Why | Ese?, etise?, nitori kini?, Kilose?, kini idire |
2 | Where | Ibo, nibo, nibiti |
3 | When | Nigbati, nigbawa |
4 | Who | Tani?, eniti |
5 | What | Kini?, kinla?, ohun ni, eyiti, ewo |
6 | How | Bawo, li ona wo, bi |
7 | Who did it? | Ta lo se? |
8 | I did it. | Emi ni mo ti se |
9 | Who is doing it? | Ta lo n se? |
10 | Who called me? | Ta lo pe mi? |
11 | Who is calling me? | Ta lo n pe mi? |
12 | Who is he calling? | Ta lo pe? |
13 | Who wants to collect? | Ta lo fe gba? |
14 | What are you doing there? | Kini o n se sibe? |
15 | What is he doing? | Ki lo n se? |
16 | Will you come? | Se iwo yoo wa? |
17 | Will he come? | Se yoo wa? |
18 | What is your NUMBER? | Kini NUMBER e? |
19 | Which NUMBER are you? | NUMBER ki le wa? |
20 | I’m at NUMBER 59 | 59 ni mo wa |
21 | Where are you? | Nibo le wa? |
S/N | ENGLISH | YORUBA |
---|---|---|
1 | Are you at home? | Se o wa ni ile? |
2 | Are you around? | Se o wa ni ayika? |
3 | Is he at home? | Se o wa ni ile? |
4 | Are they at home? | Se won wa ni ile? |
5 | Is he coming? | Se o n bo? |
6 | Are they coming? | Se won nbo? |
S/N | ENGLISH | YORUBA |
---|---|---|
1 | Does it TRANSFER? | Se ni TRANSFER? |
2 | Did you do TRANSFER? | Se e ti se TRANSFER? |
3 | I did TRANSFER. | Beni, mo ti se TRANSFER. |
4 | Did he do TRANSFER? | Se o ti se TRANSFER? |
5 | He did TRANSFER. | Oo ti se TRANSFER |
S/N | ENGLISH | YORUBA |
---|---|---|
1 | Does it TRANSFER? | Se ni TRANSFER? |
2 | Did you do TRANSFER? | Se e ti se TRANSFER? |
3 | I did TRANSFER. | Beni, mo ti se TRANSFER. |
4 | Did he do TRANSFER? | Se o ti se TRANSFER? |
5 | He did TRANSFER. | Oo ti se TRANSFER |